Ibisi Ilera abiyamo Ifeto somo bibi Gbigba abere ajesara Iku omode

NAIJIRIA
Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 2013
2013 Nigeria Demographic and Health Survey
Ibisi
Ifeto somo bibi
Apapo ibisi ni awon orile ede iwo oorun Afirika
Ibisi fun obinrin kan laarin odun meta siwaju iwadi naa
Okookan ninu awon
obinrin ile Naijiria ni
omo marun ati aabo
(5.5). Ibisi ni ila iwo
oorun Afirika wa laarin
omo merin ni orile ede
Ghana si mejo ni orile
ede Niger.
4.9
4.0
Ghana
2008
DHS
5.0
5.0
5.5
5.2
5.1
6.0
Benin Cote d’Ivoire Senegal Sierra Leone Liberia
2011-12 2011-12 2010-11
2008
2007
DHS
DHS
DHS
DHS
DHS
6.6
Nigeria Burkina Faso Mali
2013
2010
2006
DHS
DHS
DHS
7.6
Niger
2012
DHS
Ilera abiyamo
Bii ibimo merin ninu mewa ni o ni
iranlowo osise eto ilera.
Ida meedogun ninu ogorun pere
lo lo eyikeyi ninu eto ilana ifeto
somo bibi. Lilo ilana fifi eto somo
bibi wa laarin ida meta ninu
ogorun ni ila oorun ariwa si ida
mejidinlogbon ni iwo oorun gusu.
Bi lilo ilana ifeto somo bibi se
gbile si ni elekunjekun
Ida ninu ogorun awon obinrin ti o wa ni ile oko lowolowo ti
ojo ori won wa laarin odun meedogun si mokandinlaadota
ti won n lo eyikeyi ninu ilana ifeto somo bibi
<10%
>25%
10-25%
North West
4%
Iranlowo lasiko ibimo
© 2012 Akintunde Akinleye-NUHRI, Courtesy of Photoshare
Don’t know
1%
Ko si
enikankan
13%
Dokita
10%
Ibatan/elomiran
23%
Noosi/agbebi
25%
Agbebi ibile
22%
*Osise eto ilera je dokita, noosi,
agbebi, ati oluranlowo noosi/agbebi.
*Ida mejidinlogoji
ibimo ni o ni
iranlowo
osise eto ilera.
North East
3%
North Central
16%
South West
38%
South South
South East
28%
29%
Nigeria
15%
Oluranlowo noosi/agbebi
3%
Onise ilera agbegbe
2%
Gbigba abere ajesara
Iku omode
Gbigba abere ajesara ti gberu si ni
ile Naijiria. Okan ninu omo merin ti
o je osu mejila si metalelogun ni o
gba gbogbo abere ajesara.
Isiro se afihan wiwa sile gbogbo
ipele iku omode lati odun 2003.
Bi iku omode se n lo si
Bi eto abere ajesara se n lo si
Ida lona egberun iku lori awon omo ti a bi laaye
Ida lona ogorun awon omode ti o je osu mejila si
metalelogun ti o gba abere ajesara
2003 NDHS
2008 NDHS
2003 NDHS
2008 NDHS
2013 NDHS
201
2013 NDHS
157
128
54
4850 51
35 38
21
BCG
DPT 3
29
39
36
100
41 42
13
Polio 3
Measles
29
23 25 27 21
All
None
© Abt Associates Nigeria/PATHS2 Project
48 40
37
Iku omo ti ko
pe osu kan
75 69
Iku omo ti ko
pe odun kan
Iku omo ti ko
pe odun marun