South West - The DHS Program

2008 Nigeria Demographic and Health Survey (NDHS): South West
Iwadi nipa awon eniyan ati ilera won ni lle Nigeria ti ase
ni odun 2008 pese iroyin ti o peye nipa awon eniyan ati
ilera won ni ile Nigeria. Iwadi yi je ekerin kokari iwadi
nipa awon eniyan ati ilera won ti ati se ni orile ede yi.
Odiwon gbogbo ibisi ni ipinle kookan
Bi abere ajesara se gbile si
Iye omo ti obinrin kookan bi
Ida lona ogorun omowewe ti ojo ori won je osu mejila si
osu metalelogun ti o ti gba gbogbo abere ajesara ti o ye
Iwadi na wa lori awon ti a sha lati soju awon eniyon
orile ede Nigeria. O fun wa ni bi nkan se ri ni igberiko
ati awon ilu nla ni orile ede Nigeria, elekunjekun
kookan, ati, ni opolopo igba, ni ipinle kookan ninu
merindinlogoji ti owa,ati olu ilu ile Nigeria (FCT)
Number
Bi won se
daun si
Awon ebi ti ase iwadi lowore
34,070
98%
Awon obinrin ti ojo ori won je
meedogun si o kan din ladota ti ase
iwadi lowore
33,385
97%
Awon okunrin ti ojo ori won je
meedogun si o kan din logota ti ase
iwadi lowore
15,486
93%
Oyo
5.0
Ogun
5.4
Lagos
Ogun
Ondo
Osun
Nigeria South
West
10
Lagos
18
13
15
Ogun
Ondo
Ogun
42%
Osun
Oyo
81
88 83 90
Ida lona ogorun awon ti ojo ori won je meedogun si o kan din
ladota ti osi ni imo ti o peye lori aisan ti ko gboogun HIV ati AIDS
Awon obinrin
Awon okunrin
58
94 89 88
76
72 70
58
51
Ogun
Ondo
Osun
Oyo
Nigeria
South
West
Ekiti
Lagos
Ogun
Ondo
Osun
Ondo
32%
Imo ti o peye lori bi ati le yago fun kiko
arun ti ko gboogun (HIV)
Gba itoju lati owo awon ti o ni imo to peye nipa ibimo
93
Oyo
Lagos
21%
Gba itoju oyun lati owo awon ti o ni imo to peye nipa itoju oyun
77
Osun
Ekiti
33%
Osun
31%
Itoju abiyamo
87
Ondo
Nigeria
41%
South West
31%
Oyo
37%
39
Lagos
Ogun
Kikuru ni ipinle kookan
Ida lona ogorun awon obinrin ti o bi abiye
ni bii odun marun ki ato se iwadi yi
Ekiti
Lagos
Ida lona ogorun awon omo ti ojo ori re kere ju odun
marun ti won ko si ga to (ti o kuru ju fun ojo ori re)
15
Ekiti
31
* Gba gbogbo abere ajesara pelu abere ti o n dena iko fee (BCG), ita (measles) ati iwon
meta abere DPT ati abere fun idena arun romo lowo romo lese (Polio).
Ondo
4.9
21
Mooko mooka: Awon okunrin
Nigeria South
West
Ekiti
Ida lona ogorun awon ti o loko lowolowo ti ojo ori
won si je odun meedogun si mokan din laadota ti
won n lo ona igbalode lati fi feto somo bibi
28
27
Oyo
Ida lona ogorun awon okunrin ti ojo ori won je
meedogun si o kan din ladota ti won mooko mooka
96
93
92
90
85
80
77
76
37
23
Lilo ona Ifeto somo bibi
Nigeria South
West
Ekiti
59
53
23
Lagos
4.0
Ida lona ogorun awon obinrin ti ojo ori won je
meedogun si o kan din ladota ti won mooko mooka
90
84
80
78
75
70
68
Nigeria South
West
58
43
Ekiti
5.0
Osun
4.0
Mooko mooka: Awon obinrin
54
Nigeria
5.7
South West
4.5
Oyo
* Awon ti o ni imo to peye pelu dokita, noosi/agbebi, tabi awon ti oun ran agbebi lowo/agbebi.
42
37
36
23
27
Nigeria
South
West
18
Ekiti
40
38
27
27
Lagos
Ogun
33 37
20
Ondo
Osun
25
19
Oyo
* Imo ti o peye tumo si mimo wipe ki a maa lo roba idabobo ni igba ibalopo ati pe ki a ni oni balopo ti ko ko
arun ti osi je olotito kan le din ewu ki ko arun ti ko gboogun (HIV) ku, ni iwon ti amo wipe eniyon ti oju re dan
gbinrin le ni aisan HIV, ati kiko ona meji ti o wopo nipa ero ti awon eniyan ni lori bi aisa ti ko gboogun (HIV)
gbile ati bi ati le yaago fun.
Omi ti awon ebi n mu ni ipinle kookan
Ida lona ogorun awon ebi ti oni ibi ti
won ti n pon omimimu ti odara
Oyo
71%
Nigeria
56%
South West
67%
Ekiti
Osun
63%
76%
Ondo
63%
Ogun
66%
Lagos
63%
O hun elo ifintoto ti awon ti ebi ni ni ipinle kookan
Ida lona ogorun awon ebi ti oni ibi ti odara, ti a ko si pin lo
Nigeria
27%
South West
16%
Oyo
7%
Ogun
13%
Ekiti
Osun
17%
13%
Ondo
15%
Lagos
24%
Ebi ti o ni ina monamona ni ipinle kookan
Ida lona ogorun ebi ti o ni ina monamona
Oyo
62%
Nigeria
50%
South West
71%
Osun
67%
Ogun
66%
Lagos
91%
Ekiti
63%
Ondo
48%
Fun imonran si lori agejade iwadi nipa eniyan ati
ilera won ti ase ni odun 2008, e elo si:
Ni Nigeria:
National Population Commission
Plot 2031, Olusegum Obasanjo Way,
Zone 7 Wuse, PMB 0281
Abuja, Nigeria
Telephone: (234) 09 523-9173
Fax: (234) 09 523-1024
Website: www.population.gov.ng
2008 Nigeria
Demographic and
Health Survey
Fact Sheet
Ni Amerika:
MEASURE DHS, ICF Macro
11785 Beltsville Drive
Calverton, MD 20705 USA
Telephone: 301-572-0200
Fax: 301-572-0999
Website: www.measuredhs.com
Ile ise eto ikaniyan ti ile Nigeria (National population commission) ni o se iwadi 2008 NDHS. Ile
ise ICF Macro, ti ise ile ise kokari awon orile ede
(ICF International Company) ni o se iranlowo imo
ijinle iwadi naa, igbekale iwadi ati lati gbe esi
iwadi na yewo lona eto isuna ti ajo USAID-la sile
fun MEASURE DHS. Ipese owo fun iwadi naa wa
lati odo ajo USAID ati owo pajawiri ti Aare pese
fun idojuko aarun AIDS (President’s Emergency
Fund for AIDS Relief)-PEPFAR. Ajo ile ise United
Nations Population Fund (UNFPA) ni o se inawo
bi atile mo ibi ti atile se iwadi yi ati lati mo ebi ti
a o se iwadi lowo re.
South West Zone
Yoruba
State
South West Zone
Nigeria
South
West
Zone
Ekiti
Lagos
Ogun
Ondo
Osun
Oyo
Odiwon gbogbo ibisi ni elekunjekun
5.7
4.5
5.0
4.0
5.4
4.9
4.0
5.0
Awon obinrin ti ojo ori won je odun meedogun si mokandinlogun ti
won je abiyamo tabi loyun bayi (%)
23
9
8
5
12
8
5
20
Ibimo ti ko tii to odun meji lehin ibimo ti o siwaju re (%)
24
16
17
18
18
16
11
15
10
21
15
28
13
15
27
18
Awon obinrin ti o bimo ti o si gba itoju oyun lati owo awon ti o ni
imo to peye nipa itoju oyun1 (%)
58
87
93
88
90
70
94
88
Ibimo pelu iranlowo lati owo awon ti o ni imo to peye nipa
ibimo1 (%)
39
77
81
83
72
51
89
76
Awon omo ti a bi ni ile iwosan (%)
35
70
75
77
64
47
85
67
Omowewe ti ojo ori won je osu mejila si osu metalelogun ti o ti gba
gbogbo abere ajesara ti o ye2 (%)
23
43
58
53
23
37
59
31
Omowewe ti ojo ori won je osu mejila si osu metalelogun ti ko gba
abere ajesara kankan (%)
29
13
2
12
27
23
5
9
Awon omo ti ojo ori re kere ju odun marun ti won ko si ga to (ti o
ga niwonba tabi ko ga rara) (%)
41
31
33
21
42
32
31
37
Awon omo ti ojo ori won kere ju odun marun ti won ko lara (ti won
lara niwonba tabi o gbe ju) (%)
14
9
5
10
7
6
12
12
Awon omo ti ojo ori won kere ju odun marun ti iwon won kere (ti o
won niwonba tabi iwon won kere ju) (%)
23
13
9
10
18
11
13
17
Awon ebi ti o ni okere ju apo efon ITN kan eyi ti ati re pelu oogun
apefon (%)
8
6
12
9
5
5
2
2
Awon omo ti o kere ju odun marun ti won sun si abe apo efon ITN
moju ojo ti ase iwadi yi (%)
6
5
13
7
5
4
2
2
Awon aboyun ti o sun si abe apo efon ITN moju ojo ti ase iwadi yi
(ida lona ogorun) (%)
5
3
5
2
10
1
0
4
Umunwanyi di ime ndi natara ogwu SP/Fansidar uzo ugboro abua
ndi ka IPT oge ha gara nlezianya umunwanyi di ime (%)
5
6
5
6
6
5
5
8
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Nini onibalopo kan soso (%)
68/83
67/82
65/70
66/78
74/85
55/81
85/94
60/85
Lilo roba idabobo (%)
53/72
59/73
63/74
54/65
63/80
53/70
80/87
53/77
Mo wipe o seese ki eni ti oju re ndan gbirin ni arun ti ko gboogun
(HIV) (%)
66/78
78/86
80/85
87/92
64/88
66/71
88/90
68/76
Mo wip omo kekere le ko aarun tiko gboogun (HIV) nipa mimu
oyan (%)
52/59
67/59
45/64
72/60
63/56
64/70
71/41
66/63
Mo wipe ale din ewu tio wa ninu MTCT ku nipa wipe ki iya lo
oogun oto nigba iloyun (%)
28/39
28/34
21/24
48/46
15/21
17/15
11/24
23/39
Ebi ti oni ibi ti won ti n pon omimimu ti odara (%)
56
67
63
63
66
63
76
71
Ebi ti oni ina monamona (%)
50
71
63
91
66
48
67
62
Ebi ti oni ile igbonse ti odara (%)
27
16
17
24
13
15
13
7
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Obinrin/
Okunri
Mooko mooka (%)
54/77
80/90
84/92
90/96
68/76
75/80
78/93
70/85
Ko ni eko (%)
36/19
12/5
8/2
6/3
19/10
14/5
13/3
20/11
Ibisi
Ifeto somo bibi
Lilo ona igbalode bayi (awon ti o loko lowolowo ti ojo ori re si je
odun meedogun si mokan din laadota) (%)
Ilera Iya ati omo
Itoju lati ile igbebi
Abere ajesara fun omode
Eto o nje
Aisan Iba
Imo nipa aarun ti ko gboogun (HIV/AIDS)
Mo wipe ale din ewu ati ko arun tiko gboogun (HIV) ku ni pa:
Bi ile seri
Eko
Awon ti o ni imo to peye pelu dokita, noosi/agbebi, tabi awon ti oun ran agbebi lowo/agbebi. 2 Gba gbogbo abere ajesara pelu abere ti o n dena iko fee (BCG),
ita (measles) ati iwon meta abere DPT ati abere fun idena arun romo lowo romo lese (Polio)
1